Ṣaina

From Wiktionary, the free dictionary
Jump to navigation Jump to search
See also: Saina, saina, and säinä

Yoruba[edit]

Yoruba Wikipedia has an article on:
Wikipedia yo
Ṣáínà

Etymology[edit]

From English China.

Pronunciation[edit]

IPA(key): /ʃá.í.nà/

Proper noun[edit]

Ṣáínà

  1. China (a country in eastern Asia)
    • 2008, Lérè Adèyẹmí, Kò sáyè làáfin, page 2:
      Bí wọn ti ń pè é ni Rọ́ṣíà ní wọn n bèèrè rẹ̀ ní Amẹ́ríkà, àwọn ìjọba Ṣáínà fé bá orílè̟-èdè Bóluwatife ṣe nítorí Ìwàlewà.
      (please add an English translation of this quotation)
    • 2022 April 13, Eyitayọ Fauziat Oyetunji, “Shanghai pinnu láti fìyà jẹ ẹnikẹ́ni tó bá tàpá sófin ìgbélé ààrùn còrónà [Shanghai promises punishment for COVID-19 lockdown violators]”, in Ilé Akéde Nàìjíríà (Voice of Nigeria)[1]:
      Olú-ìlú ìṣòwò orílè-èdè Ṣáínà ní Shanghai ti kìlọ̀ pé ẹnikẹ́ni tí ó bá rú àwọn òfin ìgbélé ààrùn còrónà yóò jẹyán ẹ̀ níṣu.
      The Chinese commercial capital of Shanghai warned that anyone who violates COVID-19 lockdown rules will be dealt with strictly.