ịyọn nịyọn

From Wiktionary, the free dictionary
Jump to navigation Jump to search

Yoruba

[edit]

Alternative forms

[edit]

Etymology

[edit]

From ịyọ̀n (far distance) +‎ +‎ ị̀yọ̀n

Pronunciation

[edit]
  • IPA(key): /ɪ̀.jɔ̃̀ nɪ̃́.jɔ̃̀/

Noun

[edit]

ị̀yọ̀n nị́yọ̀n

  1. (Ekiti) far distance; that which is far away
    Synonyms: ị̀yọ̀n, ọ̀nà-jíjìn
    Ị̀yọ̀n nị́yọ̀n lulé rịn-ọn à?
    Their house is far away
    (literally, “It is a far place that their house is located”)
    Ị̀yọ̀n nị́yọ̀n ni mo ti rí aṣọ òfì rà, lọ́ọ̀ụ́rọ̀ kùtù lóòní
    It was at a far place that I was able to buy asọ oke clothing, early today morning