iṣegbefabo

From Wiktionary, the free dictionary
Jump to navigation Jump to search

Yoruba[edit]

Ìfẹ̀hónúhàn ìṣègbèfábo ní Amẹ́ríkà lọ́dún 1912 fún ẹ̀tọ́ obìnrin láti dìbò ní ìdìbò bí ọkùnrin máa ń ṣe ní sáà yẹn, láyé àtijọ́, nítorí pé obìnrin kò ì lè dìbò.

Etymology[edit]

From ì- (nominalizing prefix) +‎ ṣe (do) +‎ ègbè (strong support) +‎ fún (for) +‎ abo (female), literally The act of strong support for the female gender.

Pronunciation[edit]

IPA(key): /ì.ʃè.ɡ͡bè.fá.bō/

Noun[edit]

ìṣègbèfábo

  1. feminism

Related terms[edit]