asiidi

From Wiktionary, the free dictionary
Jump to navigation Jump to search

Yoruba[edit]

Etymology[edit]

From English acid.

Pronunciation[edit]

Noun[edit]

ásíìdì

  1. acid
    Synonym: omiró
    • 2023, Arojinle, 0:29–0:44 from the start, in HOW NOT TO CRY WHEN CUTTING ONION[1]:
      "Propanethial-S-oxide" yìí, gáàsì ni. Lásìkò tó wá débi ojú tó bá fara kan omi díẹ̀ tó wà lórí ojú, yóò wá di ásíìdì kan tá a mọ̀ sí "tetraoxosulphate VI acid" tí wọ́n tún pè ní "sulphuric acid".
      Propanethial-S-oxide is a gas. Upon coming in contact with eye moisture it produces an acid known as tetraoxosulphate VI acid, which is also called sulphuric acid.

Derived terms[edit]